Saturday, November 30, 2019

Ẹkú Ọjọ́ ìbí òní Mummy DE

Gbogbo akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá kí arábìnrin Atọ́nilà kú oríire ọjọ́ ìbí Kokànlélógójì
Gbogbo akẹ́kọ̀ọ́ èdè panu pọ̀ sọ pé igba ọdún ọdún kan ni láṣẹ Èdùmàrè

3 comments:

  1. Ẹ kú ọjọ́ ìbí ìyá wa, igba ọdún, oduọdkan ni. Nínú owó, ọrọ̀ atàtaiku baálẹ̀ ọrọ̀ .

    ReplyDelete
  2. Ẹ kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí yìí fa, ẹ̀mí yín á ṣe ọ̀pọ̀ láyé

    ReplyDelete
  3. Ẹ kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí yìí fa, ẹ̀mí yín á ṣe ọ̀pọ̀ láyé

    ReplyDelete

ASA DAY 2019
ASA DAY 2019
ASA DAY 2019
ASA DAY 2019
Yosa Unilorin (c)2019