Thursday, September 5, 2019

Ìkíni/ìkéde pàtàkì



ẸGBẸ́ akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá
Fáṣitì Ilorin
5/9/2019

Ìkíni/ìkéde pàtàkì

Tiwa làsà a kí wa kú ìsinmi ọlọ́jọ́ pípẹ́ fún ti ṣáá tí a parí yìí gbogbo wa ni á ó ṣe àṣeyọrí

Yorùbá ní àti òkèèrè ni olójú jíjìn ti ń mẹ́kún rẹ̀ sun èyí ni láti fi tó àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá létí wí pé àwọn aṣojú ẹgbẹ́ yìí ti ní ètò àlàálẹ̀ tó lọ́ọ̀rìn lórí ìwọsọ àṣà Yorùbá ni gbogbo ọjọ́rú.

Ẹgbẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá ti fẹ́ gbárà tuntun yọ nípa ṣíṣe kóríyá fún ẹni tí ó bá múra Yorùbá tó dára jù ni gbogbo ọjọ́ rú àti gbígbé irú ẹni bẹ́ẹ̀ sí orí ìtàkùn àgbáyé tí ẹgbẹ́ yìí.(Face of YOSA)

Ẹ̀kejì Dandan lówó orí àṣẹ ti wá láti òkè pé kí á sọ fún wa wí pé ẹni tí kò bá sanwó ọ̀sẹ̀ àṣà rẹ (level adviser) kòní bọwọ́lu (course form) rẹ̀
Torí nà arọ̀ wá wí pé tí a bá ti wọlé sáà tuntun kí á tètè sanwó wa ọ̀sẹ̀ àṣà wa #2500.

Ire ooooo.

 Olùbọwọ́lù
 SALAUDEEN, Jamaldeen Opeyemi
Ààrẹ ẹgbẹ́ YOSA


 Olùkéde ,
 Esorun Jesu-Jenyo Ìyanuoluwa
Alukoro ẹgbẹ́ YOSA.



 Ìgbé lárugẹ àti ìrọ̀rùn akẹ́kọ̀ọ́ ẹgbẹ́ yìí ló jẹwá lógún.

0 comments:

Post a Comment

ASA DAY 2019
ASA DAY 2019
ASA DAY 2019
ASA DAY 2019
Yosa Unilorin (c)2019