Optimist Gists




Monday, February 21, 2022

[BIOGRAPHY] DR. OMOLEWU, Olatubosun Christopher

 NAME:   OMOLEWU, Olatubosun ChristopherEMAIL:   omolewuolatubosun@gmail.com omolewu@yahoo.comSCHOOLS ATTENDEDOluwole Primary School, Akoka, Lagos 1985 - 1990St. Finbarr’s College, Akoka, Lagos 1990 - 1996University of Ilorin, Ilorin 2004 - 2007University of Ilorin, Ilorin  2011- 2013ACADEMIC QUALIFICATIONS: Date Awarding InstitutionsM.A. (Yoruba Language) 2013 University of IlorinB.A. (Hons) First Class in...

Tuesday, June 2, 2020

Kò s'óhun tó jọ ṣíṣí iléèwé padà lọ́wọ́ yìí- Ìjọba àpapọ̀

Ijọba apapọ ni titpa lawọn ileewe yoo ṣi wa bayii nitori bi iye awọn to n ni arun naa ṣe n fojojumọ gogo sii lorilẹede Naijiria. Igbimọ amuṣẹya ti ijsba apapọ gbe kalẹ lori arun coronavirus lo sọ bẹẹ lasiko ifọrọwerọ rẹ pẹlawọn oniroyin. Igbesẹ naa si wa lara awọn igbesẹ to wa nilẹ eyi ti igbims naa ni, pẹlu ifọwọsi aarẹ muhammadu Buhari, ṣi n tẹsiwa...

Ọmọ pupa làwọn olólùfẹ́ wa fẹ́ wò nínú fíìmù làwọn òṣèré tíátà fi ń bóra- Muka Ray

Yoruba ni oju kii ri arẹwa ko ma kii, oju to ba sì rẹwa, o di dandan ko pawo wale. Idi ree ti ọpọ awọn oṣere tiata lobinrin fi n lo ipara ibora ki wọn lee pupa ni awọ, ti oju wọn yoo si dun wo ninu ere. Gbajumọ oṣere tiata kan Muka Ray Eyiwunmi lo sisọ loju ọrọ yii lasiko to n kopa lori eto kan loju opo ikanni BBC Yoru...

Ènìyàn 416 ló ti lùgbàdì àrùn Coronavirus ní Ọjọ́ Ajé ní Naijiria

Ajọ NCDC ti kede eniyan 416 gẹgẹ bi apapọ eniyan to ni arun Coronavirus lorilẹede Naijiria ni Ọjọ Aje lorilẹede Naijiria. Ajọ NCDC naa fi ikede naa si oju opo ikansiraẹni Twitter wọn, ti apapọ awọn eniyan to ni arun naa ti wa da 10578....

Majek Fashek, gbajúgbajà akọrin Raggae jáde láyé lẹ́ni ọdún 57

Gbajugbaja akọrin raggae ni, Majẹkodunmi Fasheke ti ọpọ mọ si 'Majek Fashek' ti jade laye. Iroyin to n tẹ wa lọwọ jẹ ko di mimọ pe aṣalẹ ọjọ Aje lo dagbere pe o digboṣe. Ẹni ọdun mẹtadinlọgọta ni Majek Fashek ki o to dagbere fa...

Sunday, April 12, 2020

Ìmọ̀ràn pàtàkì lórí àrùn Covid-19

Tiwa làṣà! Láti lè dẹ́kun àjàkálẹ̀-àrùn kórokòro tí ń jà ràn-ìn-ràn-ìn káàkiri àgbáyé. Àwa olóyè ẹgbẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá ti Yunifásitì Ìlọrin ń ránwa létí pé: Kí a tẹ̀lé àwọn ìlànà àti òfin tí ìjọba gbé kalẹ̀ fún wa láti lè dẹ́kun àtànkárí àjàkálẹ̀-àrùn kórokòro tí ń jà ràn-ìn-ràn-ìn káàkiri àgbáyé. 1. 🏘Kí a gbélé ní ìwọ̀nba àsìkò tí ìjọba ní kí...

Monday, December 23, 2019

O kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí òní Kuranga Halimat Abodunde

Ará igbó , èrò ọ̀nà ẹ sáré tètè wà bá wa yọ̀ òní lọjọ́-ìbí Abodunde Ọpẹ́ lọ́wọ ọba oníbú ọrẹ fún oore ẹ̀mí gígùn. Abodunde, pẹpẹ lọ̀wú sáré àtẹ̀pẹ́ lẹsẹ̀ e tọ̀nà ní re ní re làá sọ̀rọ̀ atare.         Orógbó ló ní kí o gbó, igi ọ̀pẹ ló ní kí o pẹ́, Ọ̀gẹ̀dẹ̀ lóní kí gbà ó dẹ̀ ọ́ lọ́rùn. Wàá pẹ́, wàá sì gbélé ayé ṣe rere. ...

Wednesday, December 18, 2019

O kú ọjọ́ ìbí òní Omidan Àṣà Christiana

Òní ni ọjọ́ ìbí Omidan Oke Christiana, aṣojú réré lo jẹ́ àwokọ́se rere lo sì  jẹ́ fún gbogbo ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá níbi ká wọṣọ àṣà Yorùbá  Ọ̀gá ni kánwú láwùjọ okùta Ọ̀gá ni omidan Tiana níbi ká wọṣọ àṣà Yoruba, Ọ̀gá ni níbi kó dá àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́. Gbogbo ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá ń dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ fún igbe lárugẹ àṣà àti ìṣẹ̀ṣẹ Yoruba wọn sì kí ọ kú ọjọ́ ìbí ...

Thursday, December 12, 2019

O kú ọjọ́ ìbí òní Boluwatife

 Gbogbo akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá ló ń bá ẹ yọ̀ tí wọ́n kí ọ kú oriire òní, wọ́n ní o òní kánjú kú, o òní mọ ìnira láyé rẹ, ọdún èyí yóò jẹ ọ̀tun nínú ayé rẹ nítorí pé Ọdọọdún là ń rórógbó Ọdọọdún là ń ráwùsá Ọdọọdún là ń rọ́mọ obì lórí àtẹ O ku oriire òní Boluwatife ...

Ìgbáradì ti bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹhu fún ayẹyẹ ọdún àṣà tí yóò wáyé ní simẹ́sítà tó ń bọ̀

Ìgbáradì ti bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹhu fún ayẹyẹ ọdún àṣà tí yóò wáyé ní simẹ́sítà tó ń bọ̀ Gbogbo lẹ́bùrù ló fi orin sẹ́nu tí wọ́n sì fi ẹsẹ̀ ra ijó Ní nkan bíi agogo méjì ó kọjá ìṣẹ́jú díẹ̀ ni ìgbáradì náà bẹ̀rẹ̀. Aní àwọn ọ̀gá bí Ọ̀mọ̀wé Omolayọ̀ Ọ̀gunlọlá àti Ìyáàfin Taiwo Babátúndé ní ìkàlẹ̀ Àwọn àwòrán tí a yà ní bi ìgbáradì náà: ...

Monday, December 9, 2019

Gbogbo akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá lápapọ̀ kí Oluwakemisola kú oriire ọjọ́ ìbí

Òní ni ọjọ́ ìbí Omidan Olawumi Oluwakemisola Olúwa Toyin Gbogbo akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè ló ń bá ẹ yọ̀ tí wọ́n kí ọ kú oriire òní, wọ́n ní o òní kánjú kú, o òní mọ ìnira láyé rẹ, ọdún èyí yóò jẹ ọ̀tun nínú ayé rẹ nítorí pé Ọdọọdún là ń rórógbó Ọdọọdún là ń ráwùsá Ọdọọdún là ń rọ́mọ obì lórí àtẹ O ku oriire ò...

Friday, December 6, 2019

Ọ̀gbẹ́ni àti omidan ọ̀sẹ̀ tó yááyì jùlọ

A yan Saheed Fatimah gẹ́gẹ́ bíi omidan to múra jùlọ àti Ògúnníyì Adédayọ̀ gẹ́gẹ́ bíi ọ̀gbẹ́ni tó wọ aṣọ àṣà tó dára jùlọ nínú ìpàdé ètò ìgbáradì fún ọ̀sẹ̀ àṣà wa èyí tó ń bọ̀ lọ́nà ní kò pẹ́ kò jìnà.  Èyí wáyé láti lè mú kí àṣà ìwọsọ wa láwùjọ Yorùbá má baà parun àti pàápàá láti gbé àṣà wa ga. Àwọn méjèèjì jẹ́ ọmọ ọgọ́rùn-ún lẹ́bùrù tí a sì ṣe èyí láti mú gbogbo àwọn tó kù mọ ìwúlò àti iyì tó wà nínú kí a máa wọ aṣọ ìbílẹ̀ wa ní gbogbo ìgbà.  ...

Saturday, November 30, 2019

Ẹkú Ọjọ́ ìbí òní Mummy DE

Gbogbo akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá kí arábìnrin Atọ́nilà kú oríire ọjọ́ ìbí Kokànlélógójì Gbogbo akẹ́kọ̀ọ́ èdè panu pọ̀ sọ pé igba ọdún ọdún kan ni láṣẹ Èdùmàrè...

ASA DAY 2019
ASA DAY 2019
ASA DAY 2019
ASA DAY 2019
Yosa Unilorin (c)2019