
Tiwa làṣà!
Láti lè dẹ́kun àjàkálẹ̀-àrùn kórokòro tí ń jà ràn-ìn-ràn-ìn káàkiri àgbáyé. Àwa olóyè ẹgbẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá ti Yunifásitì Ìlọrin ń ránwa létí pé:
Kí a tẹ̀lé àwọn ìlànà àti òfin tí ìjọba gbé kalẹ̀ fún wa láti lè dẹ́kun àtànkárí àjàkálẹ̀-àrùn kórokòro tí ń jà ràn-ìn-ràn-ìn káàkiri àgbáyé.
1. 🏘Kí a gbélé ní ìwọ̀nba àsìkò tí ìjọba ní kí...