
Ijọba apapọ ni titpa lawọn ileewe yoo ṣi wa bayii nitori bi iye awọn to n ni arun naa ṣe n fojojumọ gogo sii lorilẹede Naijiria.
Igbimọ amuṣẹya ti ijsba apapọ gbe kalẹ lori arun coronavirus lo sọ bẹẹ lasiko ifọrọwerọ rẹ pẹlawọn oniroyin.
Igbesẹ naa si wa lara awọn igbesẹ to wa nilẹ eyi ti igbims naa ni, pẹlu ifọwọsi aarẹ muhammadu Buhari, ṣi n tẹsiwa...