
ẸGBẸ́ akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá
Fáṣitì Ilorin
5/9/2019
Ìkíni/ìkéde pàtàkì
Tiwa làsà a kí wa kú ìsinmi ọlọ́jọ́ pípẹ́ fún ti ṣáá tí a parí yìí gbogbo wa ni á ó ṣe àṣeyọrí
Yorùbá ní àti òkèèrè ni olójú jíjìn ti ń mẹ́kún rẹ̀ sun èyí ni láti fi tó àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá létí wí pé àwọn aṣojú ẹgbẹ́ yìí ti ní ètò àlàálẹ̀ tó lọ́ọ̀rìn lórí ìwọsọ àṣà Yorùbá ni gbogbo ọjọ́rú.
Ẹgbẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá ti fẹ́ gbárà tuntun yọ...